ORUN ANU

ORUN ANU Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from ORUN ANU, Cash advance service, Iyana church ibilade Street, Oyo.

Oru anu wa fun awon eyan ti won nidi ifowo sowopo lati ran won lowo fun adura .fun imoran tabi alaye lori page ,ete atejise si wa lori page bakannan eseun pupo.

24/03/2026

Ekaro gbogbo ile mogba ladura bi ojumon ti mon loni ilekun anu la tikó sí fú Iran rè ri tori onigbagbo ninu oro olorun ko si fun ooo, Anu la ti ko ni alatako ko bee oó wo , Ninu ile lowa ni abi lenu ise ojó re kori anu olorun gba. JESU Oluwa wa amin. please I need your comment and repost this to your lovely friend and family. thanks

22/01/2026
Gbo bi ojumon to mon loni , anu olorun koo wa o ri, lenu ise re kori anu olorun gba, lenu owo tose kori Anu la gba, orer...
22/01/2026

Gbo bi ojumon to mon loni , anu olorun koo wa o ri, lenu ise re kori anu olorun gba, lenu owo tose kori Anu la gba, orere idunun ayo ko fara han ninu aye re ibi ko ni ba oo , bi oti ja de alafia olorun kodara bo mo o, ibi gbogbo ti oba rin si ki olorun pa ibi ree kuro lona re , ijade re ayo ni o a jasi bi oba wole ayo ni aje tie LORUKO JESU. Amin

12/01/2026

Am pray for you this it's be your blessing , in this year grace and mercy of God be with you, you we not lask good thing . amen

Eko gbogbo eniyan olorun , mogba ni adura fun wa loni pe bi odun Yi ti pari lo, emin emi ati e tofi de ori awon omo ati ...
10/12/2025

Eko gbogbo eniyan olorun , mogba ni adura fun wa loni pe bi odun Yi ti pari lo, emin emi ati e tofi de ori awon omo ati gbogbo afenifere , ani ba odun yi lo LORUKO JESU , odun ti awon wo yi ti bowa yi emi ati yin lama jo se . ire opin odun , ayo opin odun , ibukun opin odun, igbega opin odun., ki olorun ko le ami ati e lowo LORUKO JESU . ayo lao fi sodun ooo . for more prayers 🙏 Post this world and share it to your friends and family . thanks.

05/11/2025

please my people can you tell us, who is love you so much.

Good morning everyone please let be together in one love.
07/09/2025

Good morning everyone please let be together in one love.

Happy new month September , bi oluwa ti be laye ami ati e ari OSU Titun yi layo bee na ni ajoo mari OSU ti boo , Septemb...
01/09/2025

Happy new month September , bi oluwa ti be laye ami ati e ari OSU Titun yi layo bee na ni ajoo mari OSU ti boo , September yi aaje OSU igbega re ogo re abuyo ibukun oluwa ko fi ile re se ibugbe ni Oruko Jesus.

Address

Iyana Church Ibilade Street
Oyo
77121

Telephone

+2348107777121

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ORUN ANU posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to ORUN ANU:

Shortcuts

Share