03/07/2023
Fast Track Learning: Eko Lona Toya https://a.co/d/bfI5eZS
Ẹ̀kọ́ Lọ́nà Tóyá jẹ́ ètò fún àwọn tí wọn kòní ànfàní àti lọ ilé ìwé kí wọn le ni anfani lati mọ̀ kọ, mọ̀ kà ní wàràǹsesà.
Ó tuń ma jẹ anfani fun awọn akẹkọ ti wọn ti sèèsì lọ si ile iwe ti kò dángájíá tàbí àwọn ti a kọ ti wọn ko gba ẹ̀kọ́.
A gbé Ẹ̀kọ́ Lọ́nà Tóyá jáde fun ìlò ojojúmọ́ àti fun ìpalẹ̀mọ́ fun ìdánwò èdè Yorùbá.
O tun dára fun awọn ọmọ ile iwe alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ati awọn ti ile iwe gíga ti wọn ni kùdìẹ̀ kudiẹ ninu kíkà ati kíkọ èdè Yorùbá
Fast Track Learning: Eko Lona Toya